Nípa oyún ṣíṣẹ́ ní ìlànà ìṣègùn òyìnbó

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀ èdè ni ó ní òfin tí ó rọ̀ mọ́ ìgbàláàyè oyún ṣíṣẹ́ àti lílo òògùn oyún ṣíṣẹ́. Ní àwọn orílẹ̀ èdè kan tí wọn ti fààyè gba oyún ṣíṣẹ́, púpọ̀ nínú àwọn oníṣègùn òyìnbó fi ara mọ́ lílo àwọn òògùn tí à ń pè ní mifepristone àti misoprostol láàrín ọ̀sẹ̀ 13 àkọ́kọ́ oyún náà. Misoprostol nìkan náà sì lè ṣiṣẹ́ ní àkókò yìí. Àwọn àmì oyún ṣíṣẹ́ pẹ̀lú òògùn kò yàtọ̀ sí ti ìgbà tí oyún bá wálẹ̀ fúnraarẹ̀. Èèyàn sì lè sẹ́yún fúnraarẹ̀ pẹ̀lú òògùn láìsí ewu.

Bi o ti N ṣiṣẹ

Àwọn èròjà tí wọn fi pèèlo òògùn ìsẹ́yún máa ń mú kí ó máa sì, kí ó sì máa ti ẹnu ilé ọmọ, èyí tí yóò mú kí ilé ọmọ súnkì tí yóò sì ti oyún náà síta.

Lẹ́yìn wákàtí kan sí méjì tí o bá lo ìwọ̀n òògùn misoprostol àkọ́kọ́, inú rẹ yóò bẹ̀rẹ̀ sí í máa fún pọ̀, ẹ̀jẹ̀ yóò sì máa jáde. Oyún máa ń sáábà wálẹ̀ láàrin wákàtí mẹ́rìnlélógun tí o bá lọ ìwọ̀n òògùn misoprostol tó kẹ́yìn. Ọ̀pọ̀ ìgbà ni kò kí ń tó bẹ́ẹ̀.

Ti O ba jẹ Ifiyesi

Ó lè rí oyún náà bí ó bá wálẹ̀, tí o bá fẹ́. Ó lè dà bí èso àjàrà tí ó dúdú díẹ̀ tàbí awọ fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ kan; ó sì lè dà bíi àpò kékeré tí nǹkan funfun bò. Bí oyún náà bá ṣe dàgbà tó ni yóò sọ bí àwọn nǹkan tí ó máa jáde yìí ṣe máa tó - ó lè kéré bíi èékánná tàbí kí ó tóbi tó àtàǹpàkò. Tí o bá rí àwọn nǹkan wọ̀nyí, ó túmọ̀ sí pé oyún náà ti wálẹ̀. Nígbà mìíràn àwọn awọ yìí lè bá ẹ̀jẹ̀ jáde tí yóò sì nira láti rí. Ní irú àsìkò báyìí, ó ní láti wá a dáadáa kí o ba à lè ríi.

Itọkasi:

Oju opo wẹẹbu yii le nilo awọn kuki alailorukọ ati ọpọlọpọ awọn iṣẹ ẹnikẹta lati ṣiṣẹ daradara. O le ka Awọn ofin & Awọn ipo wa ati Awọn ilana Ìpamọ . Nipa tẹsiwaju lati lo aaye yii o fun wa ni igbanilaaye rẹ lati ṣe eyi.